Lúùkù 11:18 BMY

18 Bí Sàtánì sì yapa sí ara rẹ̀, ìjọba rẹ̀ yóò ha ṣe dúró? Nítorí ẹ̀yin wí pé, nípa Béélísébúbù ni èmi fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.

Ka pipe ipin Lúùkù 11

Wo Lúùkù 11:18 ni o tọ