Lúùkù 11:19 BMY

19 Bí ó ba ṣe pé nípa Béélísébúbù ni èmi fi ń lé àwọn ẹ̀mí ẹ̀ṣù jáde, nípa tani àwọn ọmọ yín fi ń lé wọn jáde, nítorí náà àwọn ni yóò ṣe onídájọ́ yín.

Ka pipe ipin Lúùkù 11

Wo Lúùkù 11:19 ni o tọ