Lúùkù 11:20 BMY

20 Ṣùgbọ́n bí ó bá ṣe pé Ọlọ́run ni èmi fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde, ǹjẹ́ ìjọba Ọlọ́run dé bá yín tán.

Ka pipe ipin Lúùkù 11

Wo Lúùkù 11:20 ni o tọ