Lúùkù 11:43 BMY

43 “Ègbé ni fún yín, ẹ̀yin Farisí, àgàbàgebè! Nítorí tí ẹ̀yin fẹ́ ipò ọlá nínú sínágọ́gù, àti ìkíni ní ọjà.

Ka pipe ipin Lúùkù 11

Wo Lúùkù 11:43 ni o tọ