Lúùkù 11:44 BMY

44 “Ègbé ni fún-un yín, (ẹ̀yin akọ̀wé àti ẹ̀yin Farisí àgàbàgebè) nítorí ẹ̀yin dàbí ibojì tí kò farahàn, tí àwọn ènìyàn sì ń rìn lórí rẹ̀ láìmọ̀.”

Ka pipe ipin Lúùkù 11

Wo Lúùkù 11:44 ni o tọ