Lúùkù 11:48 BMY

48 Ǹjẹ́ ẹ̀yin jẹ́ ẹlẹ́rìí, ẹ sì ní inú dídùn sí iṣẹ́ àwọn baba yín, nítorí tí wọn pa wọ́n, ẹ̀yin sì kọ́ ibojì wọn.

Ka pipe ipin Lúùkù 11

Wo Lúùkù 11:48 ni o tọ