Lúùkù 11:49 BMY

49 Nítorí èyí ni ọgbọ́n Ọlọ́run sì se wí pé, ‘Èmi ni ó rán àwọn wòlíì àti àwọn àpósítélì sí wọn, wọn ó sì ṣe inúnibíni sí wọn.’

Ka pipe ipin Lúùkù 11

Wo Lúùkù 11:49 ni o tọ