Lúùkù 12:29 BMY

29 Kí ẹ má sì ṣe lé ohun tí ẹ ó jẹ, tàbí ohun tí ẹ ó mu, kí ẹ má sì ṣe ṣàníyàn ọkàn.

Ka pipe ipin Lúùkù 12

Wo Lúùkù 12:29 ni o tọ