Lúùkù 13:16 BMY

16 Kò sì yẹ kí a tú obìnrin yìí tí í se ọmọbìnrin Ábúráhámù sílẹ̀ ní ìdè yìí ní ọjọ́ ìsinmi, ẹni tí sàtánì ti dè, sáà wò ó láti ọdún májìdínlógún yìí wá?”

Ka pipe ipin Lúùkù 13

Wo Lúùkù 13:16 ni o tọ