Lúùkù 14:9 BMY

9 Nígbà tí ẹni tí ó pè ọ́ àti òun bá dé, a sì wí fún ọ pé, ‘Fún ọkùnrin yìí ní àyè!’ Ìwọ á sì wá fi ìtìjú mú ipò ẹ̀yìn.

Ka pipe ipin Lúùkù 14

Wo Lúùkù 14:9 ni o tọ