Lúùkù 14:8 BMY

8 “Nígbà tí ẹnìkan bá pè ọ́ wá sí ibi ìyàwó, má ṣe jókòó ní ipò ọlá; kí ó má ba à jẹ́ pé, a ó pe ẹni tí ó lọ́lá jù ọ́ lọ.

Ka pipe ipin Lúùkù 14

Wo Lúùkù 14:8 ni o tọ