Lúùkù 16:22 BMY

22 “Ó sì ṣe, alágbe kú, a sì ti ọwọ́ àwọn ańgẹ́lì gbé e lọ sí oókan-àyà Ábúráhámù: ọlọ́rọ̀ náà sì kú pẹ̀lú, a sì sin ín;

Ka pipe ipin Lúùkù 16

Wo Lúùkù 16:22 ni o tọ