Lúùkù 16:23 BMY

23 Ní ipò-òkú ni ó gbé ojú rẹ̀ sókè, ó ń bẹ nínú ìṣẹ́ oró, ó sì rí Ábúráhámù ní òkèrè, àti Lásárù ní oókan-àyà rẹ̀.

Ka pipe ipin Lúùkù 16

Wo Lúùkù 16:23 ni o tọ