Lúùkù 16:9 BMY

9 Èmi sì wí fún yín, ẹ fi mámónì àìṣòótọ́ yan ọ̀rẹ́ fún ara yín pé, nígbà tí yóò bá yẹ, kí wọn kí ó le gbà yín sí ibùjókòó wọn títí ayé.

Ka pipe ipin Lúùkù 16

Wo Lúùkù 16:9 ni o tọ