Lúùkù 19:23 BMY

23 Èé ha sì ti ṣe tí ìwọ kò fi owó mi pamọ́ sí ilé ìfowó pamọ́, pé nígbà tí mo bá dé, Èmi ìbá ti béèrè rẹ̀ pẹ̀lú èlé?’

Ka pipe ipin Lúùkù 19

Wo Lúùkù 19:23 ni o tọ