Lúùkù 19:24 BMY

24 “Ó sì wí fún àwọn tí ó dúró létí ibẹ̀ pé, ‘Ẹ gba owó mínà náà lọ́wọ́ rẹ̀, kí ẹ sì fi í fún ẹni tí ó ní owó mínà mẹ́wàá.’

Ka pipe ipin Lúùkù 19

Wo Lúùkù 19:24 ni o tọ