36 Ǹjẹ́ kì ẹ máa sọ́nà, kí ẹ sì máa gbàdúrà nígbà gbogbo, kí ẹ baà lè la gbogbo nǹkan wọ̀nyí tí yóò ṣẹlẹ̀, kí ẹ sì lè dúró níwájú Ọmọ Ènìyàn.”
Ka pipe ipin Lúùkù 21
Wo Lúùkù 21:36 ni o tọ