Lúùkù 21:6 BMY

6 “Ohun tí ẹ̀yin ń wò wọ̀nyí, ọjọ́ ń bọ̀, nígbà tí a kì yóò fi òkúta kan sílẹ̀ lórí èkejì tí a kì yóò wó lulẹ̀.”

Ka pipe ipin Lúùkù 21

Wo Lúùkù 21:6 ni o tọ