Lúùkù 21:7 BMY

7 Wọ́n sì bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀, pé, “Olùkọ́, nígbà wo ni nǹkan wọ̀nyí yóò rí bẹ́ẹ̀? Àti àmì kíní yóò wà, nígbà tí nǹkan wọ̀nyí yóò fi ṣẹ?”

Ka pipe ipin Lúùkù 21

Wo Lúùkù 21:7 ni o tọ