1 Ní ọjọ́ ìsinmi kan, Jésù ń kọjá láàrin oko ọkà; àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sì ń ya ìpẹ́ ọkà, wọ́n sì ń jẹ ẹ́.
Ka pipe ipin Lúùkù 6
Wo Lúùkù 6:1 ni o tọ