Lúùkù 7:19 BMY

19 Nígbà tí Jòhánù sì pe àwọn méjì nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ó rán wọn sọ́dọ̀ Jésù, wí pé, “Ìwọ ni ẹni tí ń bọ̀, tàbí kí a máa retí ẹlòmíràn?”

Ka pipe ipin Lúùkù 7

Wo Lúùkù 7:19 ni o tọ