Lúùkù 8:14 BMY

14 Àwọn tí ó bọ́ sínú ẹ̀gún ni àwọn, tí wọ́n gbọ́ tán, wọ́n lọ, wọn a sì fi ìtọ́jú àti ọrọ̀ àti ìrora ayé fún un pa, wọn kò sì lè so èso àsogbó.

Ka pipe ipin Lúùkù 8

Wo Lúùkù 8:14 ni o tọ