Lúùkù 8:15 BMY

15 Ṣùgbọ́n ti ilẹ̀ rere ni àwọn tí wọ́n fi ọkàn òtítọ́ àti rere gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, wọ́n dì í mú ṣinṣin, wọ́n sì fi sùúrù so èso.

Ka pipe ipin Lúùkù 8

Wo Lúùkù 8:15 ni o tọ