Lúùkù 8:43 BMY

43 Obìnrin kan tí ó sì ní ìsun ẹ̀jẹ̀ láti ìgbà ọdún méjìlá, (tí ó ná ohun gbogbo tí ó ní fún àwọn oníṣègùn), tí kò sì sí ẹnìkan tí ó lè mú un lára dá,

Ka pipe ipin Lúùkù 8

Wo Lúùkù 8:43 ni o tọ