Róòmù 1:1 BMY

1 Pọ́ọ̀lù, ìránṣẹ́ Jésù Kírísítì ẹni tí a ti pè láti jẹ́ Àpósítélì, tí a sì ti yà sọ́tọ̀ láti wàásù ìyìnrere Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Róòmù 1

Wo Róòmù 1:1 ni o tọ