Róòmù 1:14 BMY

14 Nítorí mo jẹ́ ajigbèsè sí Gíríkì àti sí àwọn ẹlòmíràn tí kì í se Gíríkì, sí àwọn ọlọ́gbọ́n àti sí àwọn aláìgbọ́n.

Ka pipe ipin Róòmù 1

Wo Róòmù 1:14 ni o tọ