Róòmù 1:19 BMY

19 Nítorí pé, nǹkan gbogbo tí a lè mọ nípa Ọlọ́run ni a ti fihàn fún wọn, nítorí Ọlọ́run ti fi í hàn fún wọn.

Ka pipe ipin Róòmù 1

Wo Róòmù 1:19 ni o tọ