Róòmù 1:24 BMY

24 Nítorí náà Ọlọ́run fà wọ́n lé ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ọkàn wọn lọ́wọ́ láti máa ṣe ohun ìríra pẹ̀lú ara wọn èyí tí kò tọ́.

Ka pipe ipin Róòmù 1

Wo Róòmù 1:24 ni o tọ