Róòmù 1:8 BMY

8 Ní àkọ́kọ́, mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nípaṣẹ̀ Jésù kírísítì fún gbogbo yín, nítorí a ń ròyìn ìgbàgbọ́ yin káàkiri gbogbo ayé.

Ka pipe ipin Róòmù 1

Wo Róòmù 1:8 ni o tọ