Róòmù 11:22 BMY

22 Nítorí náà wo ore àti ìkáànú Ọlọ́run lórí àwọn tí ó subú, ìkàánú; ṣùgbọ́n lórí ìwọ, ọrẹ, bi ìwọ bá dúró nínú ọrẹ rẹ̀; kí a má bá ké ìwọ náà kúrò.

Ka pipe ipin Róòmù 11

Wo Róòmù 11:22 ni o tọ