Róòmù 12:8 BMY

8 Tàbí ẹni tí ó ń gbani níyànjú, sí ìgbìyànjú; ẹni tí ń fi fún ni kí ó máa fi inú kan ṣe é; ẹni tí ń ṣe olórí, kí ó máa ṣe é ní ojú méjèèjì; ẹni tí ń sàánú, kí ó máa fi inú dídùn ṣe é.

Ka pipe ipin Róòmù 12

Wo Róòmù 12:8 ni o tọ