Róòmù 16:4 BMY

4 Àwọn tí wọ́n ti fi ẹ̀mí wọn wéwu nítorí mi. Kì í se èmi nìkan àti gbogbo àwọn ìjọ àwọn aláìkọlà ní ń dúpẹ́ lọ́wọ́ wọn.

Ka pipe ipin Róòmù 16

Wo Róòmù 16:4 ni o tọ