Róòmù 2:13 BMY

13 Nítorí kì í ṣe àwọn olùgbọ́ òfin ni aláre lọ́dọ̀ Ọlọ́run, ṣùgbọ́n àwọn olùṣe òfin ni a ó dáláre.

Ka pipe ipin Róòmù 2

Wo Róòmù 2:13 ni o tọ