Róòmù 2:16 BMY

16 Èyí yóò farahàn ní ọjọ́ náà nígbà tí Ọlọ́run yóò tipasẹ̀ Jésù Kírísítì ṣe ìdájọ́ àwọn àṣírí ènìyàn gẹ́gẹ́ bí ìyìn rere mi.

Ka pipe ipin Róòmù 2

Wo Róòmù 2:16 ni o tọ