Róòmù 2:21 BMY

21 Ǹjẹ́ ìwọ tí o ń kọ́ ẹlòmíràn, ìwọ kò kọ́ ara rẹ? Ìwọ tí ó ń wàásù kí ènìyàn má jalè, ìwọ ha ń jalè bí?

Ka pipe ipin Róòmù 2

Wo Róòmù 2:21 ni o tọ