Róòmù 2:24 BMY

24 Nítorí gẹ́gẹ́ bí a ti kọ́ ọ, “Orúkọ Ọlọ́run sáà di ìsọ̀rọ̀-òdì sí láàrin àwọn aláìkọlà nítorí yín,”

Ka pipe ipin Róòmù 2

Wo Róòmù 2:24 ni o tọ