Róòmù 2:4 BMY

4 Tàbí ìwọ ń gàn ọrọ̀ oore àti ìpamọ́ra àti sùúrù rẹ̀? Ìwọ kò ha mọ̀ pé oore Ọlọ́run ni ó ń fà ọ́ lọ sì ìrònúpìwàdà?

Ka pipe ipin Róòmù 2

Wo Róòmù 2:4 ni o tọ