Róòmù 3:29 BMY

29 Ọlọ́run àwọn Júù nìkan ha ni bí? Kì í ha ṣe ti àwọn aláìkọlà pẹ̀lú? Bẹ́ẹ̀ ni, ti àwọn aláìkọlà pẹ̀lú:

Ka pipe ipin Róòmù 3

Wo Róòmù 3:29 ni o tọ