Róòmù 3:7 BMY

7 Nítorí bí òtítọ́ Ọlọ́run bá di púpọ̀ sí ìyìn rẹ̀ nítorí èké mi, èéṣe tí a fi ń dá mi lẹ́jọ́ bí ẹlẹ́sẹ̀?

Ka pipe ipin Róòmù 3

Wo Róòmù 3:7 ni o tọ