Róòmù 4:13 BMY

13 Ìlérí fún Ábúráhámù àti fún irú ọmọ rẹ̀, pé, wọn ó jogún ayé, kì í ṣe nípa òfin bí kò ṣe nípa òdodo ti ìgbàgbọ́.

Ka pipe ipin Róòmù 4

Wo Róòmù 4:13 ni o tọ