Róòmù 4:6 BMY

6 Gẹ́gẹ́ bí Dáfídì pẹ̀lú ti pe olúwa rẹ̀ náà ní ẹni ìbùkún, ẹni tí Ọlọ́run ka òdodo fún láìsí ti iṣẹ́.

Ka pipe ipin Róòmù 4

Wo Róòmù 4:6 ni o tọ