Róòmù 5:1 BMY

1 Nítorí náà, níwọ̀n ìgbà tí a ti dá wa láre nípa ìgbàgbọ́, àwa ní àlàáfíà lọ́dọ̀ Ọlọ́run nípaṣẹ̀ Olúwa wa Jésù Kírísítì.

Ka pipe ipin Róòmù 5

Wo Róòmù 5:1 ni o tọ