Róòmù 5:13 BMY

13 Nítorí kí òfin tó dé, ẹ̀ṣẹ̀ ti wà láyé; ṣùgbọ́n a kò ka ẹ̀ṣẹ̀ sí ni lọ́rùn nígbà tí òfin kò sí.

Ka pipe ipin Róòmù 5

Wo Róòmù 5:13 ni o tọ