Róòmù 5:6 BMY

6 Nítorí ìgbà tí àwa jẹ́ aláìlera, ní àkókò tí ó yẹ, Kírísítì kú fún àwa aláìwà-bí-Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Róòmù 5

Wo Róòmù 5:6 ni o tọ