Róòmù 6:23 BMY

23 Nítorí ikú ni èrè ẹ̀ṣẹ̀, ṣùgbọ́n ẹ̀bùn Ọlọ́run ni ìyè àìnípẹ̀kun nípaṣẹ̀ Jésù Kírísítì Olúwa wa.

Ka pipe ipin Róòmù 6

Wo Róòmù 6:23 ni o tọ