Róòmù 7:15 BMY

15 Èmi pàápàá, kò mọ̀ ohun tí èmi ń se. Nítorí pé, ohun tí mo fẹ́ se gan an n kò se é, ṣùgbọ́n ohun tí mo kóríra ni mo ń se.

Ka pipe ipin Róòmù 7

Wo Róòmù 7:15 ni o tọ