Róòmù 7:5 BMY

5 Nítorí ìgbà tí ìfẹ́kúfẹ́ ara ń darí wa, ar ẹ̀ṣẹ̀ tí ó wà nípa òfin, ó ń ṣisẹ́ nínú àwọn ara wa láti so èso fún ikú.

Ka pipe ipin Róòmù 7

Wo Róòmù 7:5 ni o tọ