Róòmù 8:24 BMY

24 Nítorí ìrètí tí a fi gbà wá là: ṣùgbọ́n ìrètí tí a bá rí kì í se ìrètí nítorí ta ni ń retí ohun tí ó bá rí?

Ka pipe ipin Róòmù 8

Wo Róòmù 8:24 ni o tọ