Róòmù 8:36 BMY

36 Bẹ́ẹ̀ kọ́, nítorí ìwé mímọ́ sọ fún wa pé:“Nítorí yín àwa ní láti múra tan fún ikú nígbàkúgbà.Àwa dàbí àgùntàn tí ń dúró de pípa.”

Ka pipe ipin Róòmù 8

Wo Róòmù 8:36 ni o tọ