Róòmù 9:17 BMY

17 Nítorí ìwé mímọ́ wí fún Fáráò pé, Nítorí èyí ni mo ṣe gbé ọ dìde, kí èmi kí ó le fi agbára mi hàn lára rẹ, kí a sì le máa ròyìn orúkọ mi ká gbogbo ayé.

Ka pipe ipin Róòmù 9

Wo Róòmù 9:17 ni o tọ